Sie sind auf Seite 1von 55

APOSTILAS DE REZAS NA HORA DO ITEFA!

1 OLODUMARE:
IBA OLODUMARE, OBA AJIKI AJIGE. OGEGE AGBEKIYEGUN OKITIBIRITI OBA TI NAP OJO IKU DA ATERE KAIYE AWUSIKATU OBA A JOKO BIRIKITIKALE, ALABURKUKE AJIMUKUTUWE OGRIBADIGBO OBA TI FI IMOLE SE ASO BORA OLUDARE ATI, OLUFORIJI, ADIMULA OLOFIN AIYE ATI ORUN. A FUN WEN AKE WEN OWENWEN AKE BI ALA. ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA AJUWAPE ALABA ALASE LORI OHUN GBOGBO. ARABA NILA TI NMI IGBO KIJIKIJI. OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI AWAMARIDI OLUGBHUN MIMO TO ORUN. ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI EKUN AWON ASEKE. AWIMAYEHUN OLU IPA OBA AIRI. ARINU RODE OLUMORAN OKAN. ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI ORUN IBA TO TO TO .

ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE. IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE GBA TIOOBA WA NILE WA FUN MI TEMI, T AYA, T OMO, T EGBE, T OGBA . WA FI YEYE WA KI OF F ONA HAN WA. WA FI ELENI SETEMI. A LAIYE O ALAIYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE. ALUJONU ENIYAN TI NF OWO KOLE. A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO A YA BIDUN DUN DUN DUN .

2 ORIKI ELA:
IFA L L ONI, IFA L O L OLA IFA L O L O OTUNLA PELUE E ORUNMILA TO MERIN OSA DAYE IFA RO WA O, ELA RO WA O O. BI O NIBE LAPA OKUN.

KO RO MOO BO. BI O O NI WANRAN OOJUMO. IFA DI ORUNMILA BI O LO L OKO KI O WA LE O BI O LO L ODO DI WA LE O, BI O L O L ODE KI O WA LE O. MOJU BA O MOJU BA O MOJU BA O ASE ASE ASE.

ORIKI ELA:
L S O OGBO S OGBO. L S ATO S ATO. F ODUNDUN S OBA EWE F IROSUN SOSORUN R ; FOKUN S OBA OMI. F OSA S OSORUN R. -S EYIN WA S EIYN BO. WON N ELA S AYE RE. L BINU TA KUN O R RUN. OMO ARY WA N KIGBE. L DDR L O MAA SOCALE WA GBURE. L DDR! L HIZO.

ORIKI ELA:
ORUNMILA ELERIMPIN IBIKEJI OLODUMARE AJE JO GUN OBIRITI A PI JO IKU AS. OLUWA MI AMOMIMOTAN AKO MO OTAN KO SE. ABA AMO OTAN IBA SE KE. OLUWA MI OLOWA AIYERE OMO ELESEIN ILE OYIN OMO OL OPE TO S AN AN DOGI DOGI. OLUEA MI OPOKI A MU IDE S OJU EKAN KO JE. K EHUN HORA ASAKA AKUNOMO OSO GINNI T APA TI NI EWE NINI OMO OSO PA DE MOWO PA DWE MESE O MBERRE AT EPA JO

OLUWA MI IGBO OMO IYAN BIRIKITI INU ODO OMO IGBA TI N SOBE JIAJIA IKU DUDU AT EWO ORO AJ EPO M APON AGIRI ILE ILOBON A B A B OLOWA DIWERE M ARAN OLOWUA MI ATO IBA JAIYE ORO A B IKUJ IGBO OLUWA MI AJIKI OGEGE A GBAYE GUN, ODUDU TI IDU ORI EMERE OTUN ORI TI KO SAIN SE, OMO EL EJO TI NRIN ODE WA SAKA SAKA. ORUNMILA ABORU ORUNMILA ABOYE ORUNMILA ABOSISE.

3 ORIKI ORUNMILA:
IFA OLOKUN ASORO DAYO ELERIN IIPIN, IBIKEDI OLODUMARE. ORUNMILA NI BABA WA, O E AWA KO NI OBA MEJI, IFA TO OBA O ORUNMILA NI BABA WA IFA TO OBA O KA MO KA LA O KA MA TETE KU, AMOLA IFE OWODAYE. OKUNRIN DUDU OKE IGETI, OLUWA MI AMO TAN OLUNAAMI OKITIBIRITI TI NPOJO IKUDA A KO MO O TAN IBA SE , A BA MO TAN IBA SE, A BA MO TAN IBA SE. BARA PETU BABA KEKERE OKE IGETI, ORI AS TI O FI GBOGBO AYE FI OJU ORORI SI PATAPATA. A BI ARA ILU BI AJERE, ORISA TI NGEBE NKAN OLE GUN FA GUNWA OKO OKEKU. OLOMU NLA A BO NI MA RU BABA ESU ODARA ORI SA TI NGBA NI LOWO ENI TI O NI IKA NINU BABA AKERE FI INU SE OGBON, OPITAN IFE A FUN NIDA.

A TUN ORI ENI TI KO SUNWON SE, FONRON OWU KAN SOSO AJE JU OOGUN, ARA YWORAN NI IBI TI OJU RERE TI IMO WA, BABA ELEPO PUPO MA JE ADIN. ONILE ORI OKE TI NI AFOPIN EYE SAYE SORUN IBINI ATO I FI ARA TI BI OKE. OGEGE AGBE AYE GUN AGIRI ILE IL OGBON, OMO ADO BABA TI I W EWU OOGUN AJANA ETA TI I NU ORI EKUN NSE BO SURUSURU. ORISA KO AJE. OLOJHOBAN A RI APA ERAN SE OGUN, ASE EYI TI O SORO ISE. EDU OLOJA ORIBOJO OBA A TUN OMO DA BI EWU, OKURIN ATO EYIN ERIN NI FIFON OKITIBIRITI A PA OJO IKU DA. IKUFORIJI. OBA OLOFA ASUN L OLA. ERINTUNDE. OMO EJO MEJI. AKERE SOGBON. AKONI L ORAN BI IYEKAN ENI AFEDEFEYO. IKU DUDU ATEWO ORO JE PON MA PON, ORO A BA IKU J IGBO ELEEI IPIN AJE JO GUN ORUNMILA IFA OLOKUN ASORODAYO. OLOORERE AIKU JE JOOGUN. BA MI WO OMO TEMI YE O AJI PA OJO IKU DA.

ORIKI ORUNMILA:
OLODUMARE MO JI LONI MO WO GUN MERIN AYE. IGUN KINI IGUN KEJI IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI. GBOGBO IRE GBA WA TI OBA WA NI LE. WA FUN MI TEMI. TAYA TOMO TOGBE TOGBA WA FI YEYE WA. KI O OF FONA HAN WA. WA FI ENI ELENI SE TEMI. ALAYE O ALAYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE. ALUJONU ENIYAN TI NFOWO KOLE. A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EITI O BA YA KO YA. ABIDUN DUN DUN DUN ALAYE O ALAYE O. IFA WA GBO TEMI, ESU WA GBO TEMI. JEKI ENI YE MI, JEKI ENI YE MI, JEKI ENI YE MI. KI OLA SAN MI T AYA, T OMO, T IBI, T IRE, LO NIRIN PAPO NI. ILE AYE. WA JEKI AYE MI. KIOYE MI. ASE

ORIKI ORUNMILA :
ETI NIGBO INXOMO ELA. ETI INFO AWO OMONI PAXA NIFE XETI WERE DJI, OMO AGBONIREGUN, ORUNMILA TE ETI, KI O O BORRUN TI UM MA FO, IFA XETI WERE WERE DJI WERE, IFA XETI WERE. KI OGBO MOKAN XETI WERE, KI OGBO MORE DJE XETI WERE, KI OGBO MOKAN XADJAMO

OMO EGUNGUN ONIFE, TI UM XA MARIWO APA KO KI UNTO WA LONI MOTI JUBA AKO DA MO TI JUBA ASE DA MO TI JUBA ERIN MI NILE ADO ARAGBA LO TU IFE. GBOGBO IN KAN TI MO BA SO LONI KI O LO SILE ASE, ASE, ASE,

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA DAKUN DABO, AKODA KUN DABO KOYE SESE. ORUNMILA ELERIN IPIN AJE JO GUN. IBIKEJI OLODUMARE AKOKO OLOKUN ASORO DAIYO. AJA IKOTO ARA ADO ARA EWI ARA OKETASE ARA OJUMO. IBITI OJO TI NMI WAYE ARA OKE OGETI OKEJI OJE ERIN FON O LAGILAGI OKUNRIN TI NMO ARA OGDAN LE ALAKETE PENNEPE. PARI IPIN OLO TO KAN TOKU LAYE, OBA IKU JA GBA OMO RE SILE ODUDU TI NDU OR EMERE, MA BA JO OTUN ORI TI, KO SUN WON ASE ASE ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA BARA AGBONIREGUN,

ADESE OMILESE A MO KU IKUFORIJI OLIJENI, OBA LOFA ASUNLOLA NINI OMO LONI OLUBESAN ERIN TUNDE ABIKUDIGBO ALAJOGUN IGBO OBA IGDE, PARA PETU OPITAN ELUFE AMORANMOWE DA ARA RE ORUNMILA IWO LO O KO OYINBO L ONA, ODUDU PASA AKI IGBO OGUN I LAJULE ORUN DA ARA ORUNMILA A KI IFAGBA, MERINDINLOGUN AILE K ASINA MA J AMA RO LERIN IPIN IBIKEJI EDUMARE FONANHAN NI ORUNMILA IBURU IBOYE IBOSE ASE.

ADURA ORUNMILA OLUWA MI AJIKI:


ILA JI ORUNMILA, ILA JI ORUNMILA ILA JI ORUNMILA. MO JO MO KI ATOLA, MO KI ASULA. MO KI ASURUNENENE. INA KU KU L AHERE. ENIA KU KU L ABA ADIFA FUN OGOJO L IMO OGBOJO. O NI TI AWO YO OGBOJO TI AWO YO OGBOJO. NJ O LUWA MI MA JIKI TIRE YO O. AWO AJIKI L AWO AJIKI AWO AJIKI L AWO AJIKI. AWO AJIKI, L A IPE AWO AJA ALE GBHUN A DA A AWON META NLO BO ORI ELU. ORI ELU KO GB EBO LOWO WON. AWO AJIKI L AWO AJIKI. AWON AJIKI L AWO AJIKI AWO. AJIKI L AWO AJIKI. AWO AJIKI LA IPE AWO AJA ALE GHUN. A DA FUN IKI T O ON YIO BO ORI ELU. YIO GBA IBO L OWO ON. IKI JI O WEWO FINI. O WA IMU OBI O NA A SI ORI ELU.

ORI ELU GBA LOWO RE. ONI LOWO IKI ELEIYNJU EGE L A TO MI IBO E IGBANA NI IKI MEKU S EKUN IGBE. O M OHUN YERE NKORIN WIPE. GB OBI PA O! A WO AYE GB OBI PA O AWO AYE GBO OBI PA O AWO AYE ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ALAPANKO AWO MA JU AWO LO AWO LE GBAWO MI TORITORI ODIDERE FO O GORI IROKO O FI OHUN JO AGOGO LO SE IFA FUN IFAKOREDE A REMO OLODUMARE OMO ATE ENI TEM KO TO FI ORI SE AGBEJI ARA. O NI E BA MI SO FUN ALARA E PO MO RIREO NI E BA MI SO FUN AJERO E PE MO RIRE IRE TO SOUN IRE DE IRE TO SONU IRE DE BI IRE BA WOLE E JE KI A NA SUNRU SI NI INU BA LE LALE JU IRE O WOGBO AGBO YAYAI ARAIN OMOM NI SUN MO GO PORO LALEDE OMO WEERE W ABA MI HESAN OLOGBO JI GOLO AWO AWO LILE AWO OLONI ADIPON YAYA NI IGODO AWO LO SO OKA AWO LO SE ERE AWO LO EKUN LANIN AWO MAA REE AWO AWO LILE AWO ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA AJAMIRANRA AGBONIRTEGUN IBI KEJI OLODUMARE ELERIPIN OMO OPE KAN TI NI SORO DOGI DOGI ARA ADO ARA EWI ARA IGBAJO ARA IRESI,

ARA IKOLE ARA IGETI ARA OKE ITASE, ARA IWORAN IBI OJUMO TI NMO WAIYE, AKOKO OLOKUN ORO AJO MA PON, OLAGO LAGI OKUNRIN TI NMU ARA OGDAN LE, OBA IKU J GBA OMO E SI LE ODUDU TI NDU ORI EMERE O TUN ORI TI KO SUNWON SE, ORUNMILA AJEKI, ORUNMILA AJEKI, ORUNMILA NI O DI FI ORO RERE L O ASE.

ORIKI ORUNMILA:
ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE, ORUNMILA MO PE IFA MO PE, IFA MO PE, IFA MO PE, ODUDUWA MO PE ODUDUWA MO PE ODUDUWA MO PE. IGI NLA SUBU WONAKANKAN DETU ORUNMILA NI O DI DARAJ MO NI O DI DARAJI. ASE ASE ASE.

ORIKI DOS OLODUS PARA CONSAGRAO ORO OPELE E CONSAGRAO DE ORUNMILA: EJIOGBE MEJI:
ALELEKUN LOO JE E E OMI NI NKUN ERIN O SE YI PA DA KUN ATATA BI AKUN OKUNRIN KUN KUN KUN LORU AKO AJA LOLA AKO AABALA LOSU OMO ABOKUN

OMO ENI WON ABOYINDE OMO ENI OSE DI JE LEKE KAFI LEKE SI TO MO ELOMIN OMO ENI LOMO ENI JEE A DIFA FUN ORI DESE PUPA TOKE APA TITIKU TARUN NKALE RE RE AJOGUN GBOGBO NKALE RE NI LILO NI LILO ONIKUN NA SO NI BO DEDE PA ASENIA MO, ASNIA MO KI ARUN MA SE ONIBODE SE ASENIA MO ASENIA MO ASENIA MO ASENIA MO.

ODU OYEKU MEJI:


AGBA YEKU YEKU ORI GBA IGBA OWO AGBA YEKETE OSO KALE ADIFA FUN OLOMO AWAIYE KU WON NI O RUBO AIKU KO SE POPA OGUN ODUN ONIO OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN GBOIN GBOIN NI TOKE OKE OKE GBOIN GBOIN

IGBA ODU ONIO OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN GBOIN GBOIN NITOKE OKE OKE GBOIN GBOIN IGBA GBOGBO OKENBE LAIKU GBOIN GBOIN GBOIN GBOIN NITOKE OKE OKE GBOIN GBOIN

ODU IWORI MEJI:


IWORI MEJI KO BAKUN KO BA WA SE PA BI O SE DA OSE DA LAWO WON LODE TORI AKATANPO JAKUN ODO RIRI KALE ADIFA FUN ORUNMILA IFA LO NTAIYE OLUFE ORUN SOYE ENI TI SOGBA TA NI IYO WA BA WA TAIYE WA WON IY SO EWE ODEDE TI LEE SO ORUNMILA NI OBAWA TAIYE WA WON YI SO EWE ORERE TI LEE SO BA RA PETU NI YIO BA WA TAIYE WA WON YI SO EWE OPEPE TI LEE SO

ODU ODI MEJI:


ODI MEJI KODA KUN KO BA WA SE ODI MEJI DIMA IKU DIMA ARUN ODI MA KURU KURU WALE OSA ABADA OYE BATA SAKI NI O TORUN GBO BOROBORO

AFEWO ORUN DIFA, NI AS AWO OSAIN NI KARO AGBOFA ATAN GIRIGRI TI MOMI OJU SOGBERE IRE GBOGBO OTA BA WA KOWA A TAWA JO ATAN GIRIGIRI BA WA ATAWA JO OKE NI KO IWA EBE JO OBA BA WA KOWA A TAWAJO ATAN GIRIGIRI BA WA KOWA A TAWA JO

ODU IROSUN MEJI:


IFA KODAKUN KODABO KOFIYEDENU IROSU MEJI KODAKUN KO BA WA SE IBA BURU NA LAWO IBA BURU IBA BURU NA LAWO IBA BURU IBA BURU LAWO IIBARAKATA ADIFA FUN IIGBA NIJOTI IGBA TO FI NS AWO RODE OYO0 IGBA OYO NILE O IGBA EMI LEEE WA DOKO IGBA MO SEBO OLA TUTU IGBA MO SEBO OLA TUTU IGBA MO SEBO OSUN TUTU MO WA UM GBERIGI ALO TAN ARA TU MI NININI

ODU OWORIN MEJI:


IFA KO DA KUN KODABO KOFIEDENU OWORIN MEJI KO DA KUN KOBASE OWON OWO ANNAWO OWON OMI ANDESUN OWON ONIJE NI LA NPE NIRIYAN ADI AFUN YO WON TI NSOMO OBA LEYO ADUN NI OBA AJODA EEMI IGBA ARA OBA AJESE YOKUN TOOTOO LEYO ONI E SURE WA KE WA RAJA OOMO OBA ENYIN EGBO OSESE WA KE WA ROHON YOWON ESURE WAO E WA RAJA OMO OBA

ODU OBARA MEJI:


ISE OSOHUN AMUSIE IYA OSOHUN AMO SAWODA A DIFA FUN EJI OBARA TI NRA AGBON OLA TI ABOGBA ARAIYE NRI ELEGDE MEREE ELEGEDEE MEREE EJI OBARA KI NLOTA KI NLOTA TOOFI DA LAIYE ELEGEDE MEREE.

ODU OKARAN MEJI:

OYA NI OSA A RA KURU KURU OTA MANA MANA AKO APARO ABA APARO WON LAABE LORI SAI SAN LO DIFAFUN OLOFIN, OLOFIN NROTE WON NI O GBODO KUTE ONASE AYA RE NSOJOJO ARUN WON NI O GBODO KU ARUN OKAN BI OMO RE NI SO REGDE WON NI E E FOREGDE KU ONI DUDU GBA DUDU ONI PUPA GBA PUPA ALAYIRIN GBA AYIRIN BARA PETU OBA MAMA KOKU O KARUN BARA PETU

ODU OGUNDA MEJI:


OGUNDA MEJI AWO BOM LO DIFAFUN BON NIGBATI NIFI NJE NI ROPO OTA ENU TI IBON FI NFOHUN LOFI ISEGUN EROPO EROOFA E WA BA WA ISEGUN ARUISEGUN LAA BA NI LESE OBA ORISA

ODU OSA MEJI:


OSA MEJI KODAKUN KOBA WA SE

OSA MEJI LA KOJA OOGUN YANKAN YANKAN LOJU OPON ADIFA FUN OLUBAMBI OLUKOSO LALU OMO ARIGBA OTA ISEGUN NIGBA TI SANGO NFE NI BE LARIN OSIRI TI OLUBAMBI TOFI NBE LARIN OTAA AIYE NJE LARIRA FI SETE LIGB OTA LIGBOTA LARIRA FI SETE LIGBOTA.

ODU IKA MEJI:


IKA MEJI KODA KUN KO BA WA SE BA FADAKA BA PADAKA ADAKA OOSALA NLO MASO AKADAKA AKARA KARA OJU KANGANRAN OKANJO ENIA DAWOJO WOKE YANYAN EJO NI O OKOMO TIE LEHIN YO YO YO MAJE KANO OKO ADIA DUN ALAYINRIN OKEPE NIGBATI NFE NJE NIROGBUN OTA ONI LAO PA YI NRIN OLALAO PA YI NRIN ENIKAN O LEE PA YI NRI MA O

TITUN LA TA YI NRIN SE AYINRIN MAMO DE ARA OODE IWOYA ODARA OODE IWOYA ARA OODE LWOYA ONI LAOO PA YI NRIN OLALAOO PA YI NRIN ENI KAN O LEE PA YI NRIN ENIKAN O LEE PA YI NRIN MOO TITUN LA TA YI NRIN SE AYINRIN MAMA DE ARA ODE LWOYA

ODU OTUROPON MEJI:


OTURUPON MEJI ANI OSOHUN TO DOA ADIFA FUN GANNI GANNI OKE EYO TI O MA SOWO EGAN KIRI KARI AIYE AWA MAMA LOWO KEE MA YAN WA O GANNIGANNI EGAN O POYN MA DUN GANNI GANNI MO MO LOWO NLE EMO GAN MI O GANNI GANNI EGAJN O POYIN MA DUN GANNI GANNI MO BIMO KUNLE EMO GAN MI

GANNI GANNI EGAN OPOYIN MADUN GANNI GANNI

ODU OTURA MEJI:


AGBADA BALE OROKOGO ITEWU BALE SE SII ADIFA FUN BABAMALE BEWO GEREJE TI O MA FI GBOGBO AIYE SO FE JE KIN LAJE NI LLARE E WA IFA

ODU IRETE MEJI:


ERUNYAN NFODO KETE ADIFA FUN ATOKAA EEYI TI SE LARIO OLODUMARE LLARI OBA OROKO EMI IIBA SE ILARI IFA EMI AAYO SESE LLARI OOBA OROKO ERO IPO ERO OFA ENYIN OMO PE ILARI IFA LEMI SE

ODU OSE MEJI


AGBALAKEE LA LE ADIFA FUN ORUNMILA

IFA OO ISEGUN LAIYE IFA OO SE TORUN IFA ISEGUN LAIYE IFA SE TORUN ASE KOSI IRONMOLE BII IFA IFA ISEGUN LAIYE IFA SE TORUN KO SI IRUNMIOLE BII IFA

ODU OFUN MEJI:


IFA NI ADEOWOLE LAWO ALAJIKI AIYETUTU LOWO AJIWORAN RERE ADIFA FUN ORUNMILA IFA TOLOREGBE AIYE TUTU NIYAWO NJE IJIALO LO REGBE AIYETUTU NIYAWO AIYE IFA TUTU OJOMILO O ONI AIYE IFA TUTU JOMILOOOO AIYE IFATOTO OJOMILO YIAWO LO OGBE AIYE IFATOTO NIYAWO AIYE TOTO OJOMILO

ORIKI OLODUMARE, DOS ODUS QUE SE USA PARA CARREGAR EXU E ORIKI DE EXU : 1 OLODUMARE:
IBA OLODUMARE, OBA AJIKI AJIGE. OGEGE AGBEKIYEGUN OKITIBIRITI OBA TI NAP OJO IKU DA ATERE KAIYE AWUSIKATU OBA A JOKO BIRIKITIKALE, ALABURKUKE

AJIMUKUTUWE OGRIBADIGBO OBA TI FI IMOLE SE ASO BORA OLUDARE ATI, OLUFORIJI, ADIMULA OLOFIN AIYE ATI ORUN. A FUN WEN AKE WEN OWENWEN AKE BI ALA. ALATE AJIPA OLOFA ORO OB A DEKA DAJO AWOSU SEKAN. OBA AJUWAPE ALABA ALASE LORI OHUN GBOGBO. ARABA NILA TI NMI IGBO KIJIKIJI. OYIGIYIGI OBA AKIKU ATI OBA NIGBO, OBA ATENILE FORIGBEDI AWAMARIDI OLUGBHUN MIMO TO ORUN. ELA FUNFUN GBO O OBA TOTO BI ARO, PAMUPAMU DIGIJIGI EKUN AWON ASEKE. AWIMAYEHUN OLU IPA OBA AIRI. ARINU RODE OLUMORAN OKAN. ABOWO GBOGBOGBO TI YO OMO RE, NINU OGIN AIYE ATI ORUN IBA TO TO TO .

ORIKI OLODUMARE:
OLODUMARE MOJILONI MO WO GUN MERIN AYE. IGUN KINI, IGUN KETA IGUN KERIN OLOJO ONI GBOGBO IRE GBA TIOOBA WA NILE WA FUN MI TEMI, T AYA, T OMO, T EGBE, T OGBA . WA FI YEYE WA KI OF F ONA HAN WA. WA FI ELENI SETEMI. A LAIYE O ALAIYE O. AFUYEGEGEGE MESEEGBE. ALUJONU ENIYAN TI NF OWO KOLE. A NI KOSI IGI MEJI NINU IGBO BI OBI EYITI O BA A YA KO A YA BIDUN DUN DUN DUN .

ODUS QUE SE CARREGA ESU: OSETURA:

OSETURA LADAFUN UNIBATILO LEAJA BENIJO

TETE NO NSJO INDA OIYN AFERE EWEWE AIYANA DIDE AFERE WEWE AYABA DIDE AFERE WEWE OSETURA OMI UNROSO ATI ASHA OLODUMARE EBO MORESILE ODARA

ODU OSETURA:
OSETURA AWON ALARA LODIFA FUN ALARA OMO AMURIN KANDAGBA AGOGO IDE PSETURA AWO AJERO LODIFA FUN AJERO OMO OGBOLU KORO IJALE AJESE OGANNA IMASE ADIFA FUN OSETERE OMO BUBA OYE OSEKE O JE KOMU OSE NGBE BO RORUN WAYI IGBA NI OLUO DIDE OKIKI EBO ASI KANKUN AWA TETERU KOTETEDA KEBO WA OTELEDELE OLODUMARE

ODU OSETURA:
OSE OTURA GBA ERU KI EBO FIN GBA ERU KI EBO DA GBA ERU KI EBO DODE ORUN DAN DAN DAN OSETURA TURA TURA TURA OSE TURA (JUGANDO COM PALAVRAS) DIFA FUN APARO YEYE O NRE OKO ALERO L ODUN IKU KII MO ILE ELEBO ERO ONAKAN KII I MO ILE APARO

NKAN BURUKU KO NI MO ILE MI TO NI TI OLUWO TUFEEEE NI TI JUGBONA ORO TI AWO BA SO S ILE A DI EGUN DIFA FUN ARUGBO A BI ETI KOKO O NLO BA WON NA OJA EJIGBOMEKUM TI OUN ASE L OWO AKUKO NDA AJA ENI BA TI SUN KO DIDE

ODU OSETURA:
OSETURA LADAFUN ONI BA TILO LEAJA BENIJO TETE NO NISHO INBA OYIN AFERE WEWE AIYANA DIDE ARERE WEWE PSETURA OMI UNROSO ATIE ASHA OLODUMARE EBO MO IRE ODARA

ODU OSETURA:
PENPE LESEE ELA AGEMO NI O TO GELE IBA TO GELE NBA UM RELE LOO WE AD IFAFUN AWURELA TI N SAWO RODE IJEBU APEJIN LAA PE AWURELA NI JEBU OSE AWURELE AWO IRE NI O

ORIKI ODU OWORIN SOGBE PARA CARREGAR ESU: ODU OWORIN SOGBE:
ESU KU ORI EGBA KU ORI A DIFA FUN WON NIJESA OMO EKUN

A DIFA FUN WONNI JESA OMO ERAN A DIFA FUN ONI JESA OMO ENI ALABE MA NRINGBATIE KO MA NYAA LO OWORIN SOGBE KE ESU EGBA OWORIN SOGBE KE ESU EGBA OWORIN SOGBE KE ESU EGBA

ORIKI ODU OWORIN SOGBE:


OWORINSHONGBE TABAKOYU BAIN IKU BAIN BAIN JOBATI ADIFA FUN OUN BABALAWO MERIDILOGUN TINLODIFA ILE OLOFIN

ORIKI ODU OWORIN SOGBE:


OORE NI IGUN SE NI IGUN FI PA L ORI OORE NI AKALA SE NI AKALA FI YO GEGE L ORUN IJO MII IJO MII KI ENI MA SE OORE MIO DIFA FUN IJIMERE TI NLO BA OLOKUN PESAN ODUN WON NI KO RU BO OGB EBO O RU EGBE MI O PEERE PEKUN OPE

ODU OKARAN SA PARA CARREGAR SEU: ORIKI ODU OKARAN AS:


OKARAN AS AWO EJO LO DIFA FEJO EJO NBE LAARIN OTA NJE ITAKUN LAARIN OTA NJE ITAKUN LEJO TI OBA SI ORI A BA MEJO DI IGI ITAKUN LEJO KI ORI GBE WA NIJA

ODU OKARAN SA:


OKARANSA MUKISI BILARI ONE BABALAWO BILORI OMA BABALAWO LORUN KABOLOSI OBAKARANSA KOSHE SHANDO ELO ADAMAKOSI BILOR KOGUN GUN GUN ADIFAFUN IKOKO

ODU OKARAN SA:


ALEERE BIDI PETE A D IFA FUN OWOOMO ASEKU MODI OSIKALEKA NI NFI OWO OTUN GBE EBO FUNMI NI KI TOSI IGBA MOFI OTUN GBE FUN MOSIFI GBAA TOBA GORI OPON KOFIN TOBA OWO TOBA KANLE TAN ORN ELEBO NI NLO

ODU OKARAN SA:


OKARAN SA IYA IGBA O LE MO ON WE KOMO RE O BERI LO A D IFA FUN TENTERE OPE

TI NLO RERE GBE ELEBO LEKE NJE BIKU NBO WA KO GBE ELEBO LEKE TENTETE OPE GBE ELEBO LEKE NJE BIKU NBO WA KO GBE ELEBO TENTERE OPE GBE ELEBO LEKE

ORIKI DE ESU NA HORA DO ORO

ORIKI EXU 2 ORIKI ES


Iba Esu Lalu Esu oga onilu Etobajaiye eleso ogun Otili loogun Aigada eye Oroko-ni-ojo-ebo-Ie Esu tabirigbongbon Abonijawa-kumo Esu olafe aseni-bani daro Esu iwo 10 se babalawo Ojo metadinlogun 10 gbe odo oya

Esu ma se mi omo elemiran ni 0 se Esu ma se mi lu enia lumi Esu ki nkan ma se omo mi Esu ki nkan ma se awon ara ile mi Ma jeki a ri ija re Iwo se oba ti won ti yo loye Iwo se iyawo ti 0 fi ko oko re sile Esu ma se mi omo elomiran ni 0 se Iwo se enia to fi binu soku Iwo se enia to fi ko soda Esu ma se mi omo elomiran ni 0 se Ibukun pupo ni emi fe lodo re Esu iwo ni ilera Abo igbega ire oro mbe Iowa re Jowo ki 0 wa fun mi ni nkan wonyi Esu elegbara gbo mi kiakia Esu ma se mi omo elomiran ni ki 0 se Ase ti Eledunmare Eledunmare Ase

ORIKI ES

ALAKEGUN K RINGUN IERI OJINLE AERE K RAIE MOKUNTELE ARINJINA K ROJU RO MO RE TOL JE KARON KARON GBE TIUA GBO JE KARON KARON SORO ARA UA JE KARON KARON GBE TAIE TARA UA ORUK IF O LAPE ORUKO IF O LAPE MO GBAIE PEFA E GBA MIO EGBA MILA AI TOTO O E DARIJU MIO EIN MOPE KASORIKI IF KASORIKI S S BURUKU , S ON S ABENUGAN, S ORIT ORUKO GBOGBO IN MI MOPE LA PEPO EJE OIE MI O LORUKO IYA MI OSORONG ATOJE NUA TOKAN JE DO EJ OIE MI KALE O

ORIKI ES S, S DR, S, LLU KIRI K. KNRIN OR ITA, A JO LANGA LANGA LLU. A RIN LANGA LANGA LLU. ODE IBI IJA DE MOLE. IJA NI OTARU BA DELE IFE TO FI DE OM WON. ORO EX, TO TO TO AKONI. A O FI IDA RE LALE. S M SE MI O. EX M SE MI O. EX M SE MI O. OMO ELOMIRAN NI K O SE. PA ADO ASUBI DA. NO ADO ASURE SI WA SE

ORIKI ES

Exu ota orisa, osetura ni orukobaba mo o.alagogo ija ni oruko iya npe e, Exu odara , omokunri idolofin, o Le sonso si ori esse elese Ko j ko j ki eni nje gbe mi, akii lowo lai um ti exu kuro, akii loyo lai um ti exu kuro, asontun se osi lai ni itiju, exu apata somo olomo lenu, o fi okuta dipo yio, Loogemo orum , nla kalu, paapa wara , a tuka mase as exu mase mi Omo elomiran ni ose exu laroiye , ase ase

ORIKI ESU

Iba exu odara , a BA ni wa oran ba o ri da , o san sokoto penpe ti nse onibode olorum, Oba ni il ketu, Alakesi emeren aji e aji e m u, ogun, a lun se , wa se ibini , laguna J igbo bi oro Exu foli Fo o fi oko Fo oju anan re La nyan hamana, ika ko boro boro, ko La ko Ra o ba ona oja il su agbo l ara a yaba ma PA mo, abemu, o se firi oko erro oja Bara fi imu fon awon sebi oko l o si , ero palemo wara wara.

ORIKI ES
Esu eni enire eni enire ki lana koma la eni enire Enire titi enire dalaku lana cwo lana Omo Lana alafia fin mi seu mase mi Omo Eloniran ni 0 se.

ORIKI ES
Iba Eu ogri oko abaneworan ba 0 rida Eu apatapiti apitipata 0 da okuta si iyo oniyo Eu ma se mi omo elemirim ni ose.

ORIKI ES Ojumo ti mo mo PE Eu odara ranse Ojumo ti mo mo ki legbara Ojumo 0 mo fun mi Ko mure mi ko mi

Ork s Laro y Alktu aki Alktu. s Alaketu Or mi ma je nko o. s Alktu BA Nse ki imo. s Alktu kr o ba onimimi. s Alaketu, fun mi ofo ase, mo pl rsa. s Alaketu alajiki juba. se.

ORIKI ESU YANGI


s, Bb Als, Ki nnkan m se omo mi Ki nnkan m se aya mi ti mi n

M se mi lu niyn, m se nyn lu mi Ln ow, ln omo kn mi o s m se m, omo elmrn ni o se Asro lgo aktpe lgb lrn m j ki ar j s o

Ork fn s s pl o, okanamaho, ayanrabata awo he oja oyinsese, seguri alabaja, olofin apekayu, amonise gun mapo Nko o s, ba nse ki imo s, keru o ba onimimi s, fun mi ofo ase mo pele rs s, alayiki a juba se

ORIKI DOS ODUS QUE CARREGAM ORI: ODU EDIOGBE MEJI:


ORI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOWO ASENU A DIFA FUN OKANKAN LENIRUWO IRUNMOLE

NIGBA TI WON N TORUN BO WA ILE AYE ORI LO KOKO DA ORUNMILA DA SI OKE IGETI ORI KOO DA MI RE ORI LO DS OSUN SODE IJUMU ORI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOO ASENU ORI KOO DA MI RE ORI LO DA OBATALA SODE IFON ORI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOWO ASENU OKRI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOWO ASENU ORI KOO DA MI RE ORI LO DA AWON IYA MI AJE SODE OTA ORI KOO DA MI RE ORISA MA JHEE N SOWO ASENU ORI KOO DA MI RE ORI LO DA SANGO SODE KOSO ORI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOWO ASENU ORI KOO DA MI RE ORI LODA OYA SI ILE IRA ORI KOO DA MI RE ORI LO DA OGUN SI IRE ORI KOO DA MI RE ORI LO DA ESU SI KETU

ORI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOWO ASENU ORI KOO DA MI RE ORI LO DA ORISA OKO SI IRAWO AGBA ORI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOWO ASENU ORI KOO DA MI RE ORI LO DA EEGU SI ILE JE ORI KOO DA MI RE ORISA MA JEE N SOWO ASENU ORI KOO DA MI RE

ODU OYEKU MEJI:


OYE IHIN OYE OHUN A DIFA FUN OLOYE GELE OMO ORI RERE T N RU BI OSE KIN LORI RERE TI N RU OFULEFULE N LORI N GBEMI DOYE A FII JOBA OFULEFULE

IWORI MEJI:
ORI SE MI RERE ORI SE MI RERE OLUWO IGI MEJE NI N BE LODE ISALOYE APA N GBOKO APA N DADE

ORUURU WON A WEWU EJE KANLE GBONGBO GBON OLOGUNSESE WON A SIN OMO OKUN KANRUN BE RERE IROKO WON A YABIRA NIBA [ ARIWONYANGUI AWO WON NILE ALADO ADANLA AWO WON ODE IJESA KOTO ONA NII SAWO IMUJIN GBUGBUUNGBU A DIFA FUN ORUNMILA NIJOTI TI NSUNKUN OMO LO SII ODE IJESA NJE OMO NI MO BI TA LARA WA MI WON UM JE OWA OGA OGEE GBEBU OMO EPO YEYE OMO EPO KAN SI SII SI LEYIN TENA OMO NI MO BI TAN LARA TU MI WON UM JE OBA OLOOTU IFE RERE OMO NI MO BI TAN LAR AJO WON UM JE ONIGBAAJO ILOSI OMO A DISAN MEMU OMO NI MO BI TAN NI WON MOWOO TA WON UM JE OLOWO OMO ARA GEJGEJE OMO NO MO BI TAN NI WON JELULU TA WON MU JE ELEJELUU OMO ARIGBA ELUKUKUU KE ESU KO SEEYAN TO MO IKE SU BI ELEJELU ELEJELU PELE O OMO ARIGBA ELU KUKUU KE SU IKIN MI AGBOGBO IKIN MO ABOTO

OPE TEE RE EREKE ADO O EIRIGI ABOLA IKIN TEE RE E YI O ERIGI ABOLA

ODU ODI MEJI:


ODIDI KIRIDI AWO ORI LO SEFA FUN ORI ODIDI KIRIDI AWOO GBOGBO ARA LO SEFA FUN GBOGBO ARA NIJO TI WON N BO WALE AYE WON NI WON O KAALE KI WON O SEBO NIGBA TI APA DE APA WAA BORI DURO KEREKERE ORII MI O SAI DELENI KEREKERE NIGBA TI ESSE DE ESSE WAA BORI DURO KEREKERE ORII MI O SAL DELENI KEREKERE

IROSUN MEJI
OBA OJU OJU AS BO SINUU KOOKO OJU BA BUUBU

O BA KOOKO O SA BO SINU OJU OJU WA N SE MONPE MONPE A D IFA FUN EJI IROSUN NIJO TI N SUNKUUN PE OUN O NIBUDO WON NI KO KAALE SEBO INA KU INA FEERU BOJU OSUN KU OSUN FEGUN AALA SILE EGIN AALA GBOJU OLORUN SABA GEGEEGE A DIFA FUN LABAALE OMO EGBA ALAKE NIJO TI N FOMI OJU SERAHUN IRE GBOGBO NI NINI WON NI ORII RE NI KO BO O SI GBEBO NBE O RUBO NJE KIN NI O WAA SO IL DOJA FAWO SESEEGA NI O SO IL DOJA FAWO [SESEEGA SESEEGA YI O SAI SOJA DILE

ODU OWORIN MEJI:


AHORANGBON LAWO LODE ORE AHORANGBON LAWO ODE IJESA

AGBA KAN HANRANGBON HANRANGBON LA DE LOKUN MOLE KA TOO JAGUN IGBOHIN AYE LE KOKOOKO A DIFA FUN LAWUSI OKOLE OMO AFIROKO SEHUN EBO NIJO AYE E RE LE KOKOOKO BI OTA O BORI BORI ORII RE PA NIBI TI GBE N BORI BEE LORAAN RE O DARA O BOOSA BOOSA TITIITI IGBA OOSA SI JU BEE LOROO RE O SUNWON WON LEEGUN NI KO MOO BO O BOOGTUN BOOGUN BOOGUN IBOJI JIN GBURUGUDU LAWUSI NI HAA EBORA O LE GBE OUN MO IGBA O SE GBOGBO E TI O GUN O BA TO AWON BABALAWO E LO WON NI ORI OLORI NI O BO KAAKIRI TI ORAAN RE O TI O GUN REGE YOO SI BO ENU ELENU WON NI KO SE IJE

KO SE IMU KO SI PE GBOGBO AWON EEYAN JO ARAYE BA N WURE OHUN YOOWO TOO BA TORII RE SE KO DARA ORII LAWUSA BA GBA GBOGBO IWURE YI

NIRE BA DE NJE ORI LA BA BO A BA FORISA SILE JKIN LA N BO NIFE KA TOO BO IKIN ENU ENIYAN

ODU OBARA MEJI:


EMI LEMI IGODO AYAN LAYAN IBARA AWO KOTO KOTO KOTO OOUN LOJUU MI O TO A DIFA FUN AHUN TO TORI IRE GBOGBO DI FA A D IFA FUN AHUN EYIN TO ORI IRE GBOGBO ADIFA NJE O MO DO KO AWEDORO ORI RERE TI AHUN NI O O MO DOKO AWEDORO

ODU OKARAN MEJI:


AGBELE GBIBO ARAYE O MOO PE SIN EEGUN GBOGBO ARAYE NI N PE SIN EEGUN OBA OMINRINNIPASA LORUKO TI AA PE ORUNMILA OYEKU MEJI LO TE ORUNMILA NIFA O NI GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN ORUNMILA ATOBA ATIJOYE GBOGBO O WON NI N FORII BALE FUN IFA WON N FORI BALEE FUN IKIN BABA BORI JAJAJIGI LORUKO A PE OSANYIN

IWORI MEJI LOTE OSANYIN NIFA O NI GBOGBO AYE NI O PEE SIN OSANYIN GBOGBO AYE NIN NPE E JOO SIN OSANYIN AFUNKEKE FALA JAYE LORUKO TI A PE ORISA OBATALA ODI MEJI LO TE OBATALA NIFA O NI GBOGBO AYE NI O MOOPE JO SIN OBATALA GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN OOSA LLAWE A JAYE GBINDINGBINDIN MO SAAN KU LORUKO A PE OSUN IROSUN MEJI TE OSUN IFA O NI GBOGBO AYE NI O MOO PE SIN OSUN GBOGBO AYE NI N PEE JO SIN IWO OSUN AJEJEJE UM JAIGBO LORUKO O A IWO LLEELE OWONRIN MEJI LO TE ILEELE NIFA O NI GBOGBO ARAYE NI O MOO PE SIN LLEELE GBOGBO ARAYE NI N PE SIN LLEELE SALUJE MO JOMO AWO LORUKO TI AA PE EYIN IYAMI AJE OBARA MEJI LO TE IYAMI AJE NIFAO NI GBOGBO ARAYE NI O MOO PE SIN EYIN IYAMI AJE GBOGBO ARAYE NI N PE JO SIN EYIN IYAMI AJE SE KII ALAGBAJA TE FII ALAALAAGBAJA LORUKO TI A PE SEU ODARA NIFE OOYE OKANRAN MEJI LO TE IWO SEU ODARA NIFA O NI GBOGBO AYE NI O MON PE JOO SIN IWO SEU ODARA IFA O TO GEGE KOMO ARAYE O MOO PEJO WAA SIN MI O ORI KAN SOSOOSO O TO GEGE ORUNMILA O TO GEGE KOMO ARAYE O WAA FI RERE OWOO WON FUN MI

ORI KA SOSOOSO LORUKOO NI EWE OJUSAAJU LO NI WON O MOO GBE RERE SE ISAAJUU MI ORI MEJI NI O GBODO SI ORII TEMI NIKAN SOSO NI KO WA DENI APESIN ORI KAN SOSOOSO LORUKO NI IFA O TO GEGEEGE KOO WAA SERE TEMI FUN MI OGBE MEJEEJO EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA BABALAWO LODE ISALAYE EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA BABALAWO LODE ISALAYE EYIN LEE PE SIKITI TI E E LA OGBERI LODE ISLAYE

ODU OGUNDA MEJI: Orunmila lo dodede nibere Ifa mo ni to lo to alasaan BA oruko Sango ni oun to alassan BA rokun Won ni nje boo BA rin titi Bo o ba burib burin Bo o ba de koso Ilee babaa re nko Bi won BA se gbegiri Bi won BA roka Bi won ba bun o lorogbo Atakuka adiee kan nko

Sango ni bi mo ba ti yp tan N o pada silee mi ni Won ni sango o to alassan BA rokun Orunmila lo dodede nibere Ifa mo ni ta lo to alasaan BA rokun Oya ni oun to alasaan BA rokun Won ni nje to o bar in titi Bo o ba burin burin Bo o ba dele ira Ilee babaa re nko Bi won BA poda to tobi Bi won ba fun o ni ikoko egboo kan nko Oya ni bi mo ba ti yo tan N o pada silee mi ni Won ni oya o to alasaan BA rokun Orunmila lo dodede nibere Ifa mo ni ta lo to alasaan ba rokun Oosaala ni oun to alasaan BA rokun Nje boo bar in titi Bo o ba burin burin

Bo o ba dele ifon Ilee baba a re nko Bi won PA agbebo adie to royin sinu Bi won ba mu igba igbin Ti won ti se ni osiki nko Oosaala ni bi mo BA ti yo tan N o pada sile e mi ni

Osa meji
Ahoeo lo ni di Ni n lo ree fihaa jokoo A d ifa fun molamela Nijo to loun n loo Ra ore leru A d ifa fun oge eyi ti won ni o rubo Ko Le baa ri eru to sunwon Ra O ba rubo O ba kori soko eru O debe lo ori ore Ore wu u pupo O bara a O dele tan ni ore n sise Ibuu molamela n dun

Oun waa Le bo loko eru Ni ore naa rubo si Won ni koun naa o rubo Won ni ko bo ori e Ore naa BA rubo Won ni ko Ru ebiti Ko sir u agbon meridinlogun O si sehum o rubo Won BA gba iyerosun ifa si ebiti ohum Won ni ko de si eti oko ti n RO won ni nijo ti ebiti ohun BA um ekute Ojo naa ni o boo loko eru Ore BA se bee O de ebiti ohun o to iwon orun meji Ko um nnkankan O BA FEE kaaare Ojo to pinnu PE oun o nii de ebiti ohun Lojo naa lo PA eku eda Ekute ohun waa tobi pupo Sugbon ibi ori ekute ni ebiti um

Ika meji
Aagba

Oun won ni won joo se inu igbo Ijokun Oun won ni won joo se ile lodan Keekee Oun won ni won joo se oyo ajakaye A d ifa fun olouweri Eyi ti won ni o rubo Ko bori e Nijo ti b loo gbe oko niyawo Nje ogbere Omo oko Ori lo mo ibi oko n re o Eni Toto lati BA eni wa nnkan La n PE ri ori

Oturupon meji
Ologbon kan o gbon gbon gbon Ko ta koko omi meti aso
ENIYAN KAN O MORAN MORAN KO MOYE EEPE ILE ENIYAN KAN O SI JE ALARINNAKA KO PE OUN MO IBI ILE GBE PEKUN A D IFA FUN ORUNMILA NIJO TI N F OMI OJU S OGBERE OMO ORUNMILA FEYAWO FEYAWO

OKANKAN O ROMO BI O SI FI FE WON DORRI MERIDINLOGUN OUN WAA LE BIMO BAYII WON NI KI ORUNMILA O RUBO SI ORII RE WON NI KII SE WORO KASN NI YOO BII PAAPAA ORUNMILA BA RUBO ORII RE BA GBE EBO DODO ENI KE JI ORUN OSU OHUN NI GBOGBO AWON IYAWO ORUNMILA MEREERINDINLOGUN LOYUN NI WON BA N BIMO GBOGBO O WON SI JE OKUNRIN BI AWON ENIYAN O BAA WI WON A PE ORUNMILA BI OMO ORUNMILA O PEE IRO O BABA LOUN BI OUN O BIMO DIPO KI WON O MOO PE OMO ALAWO WON BA N PE BABA ALAWO BEE NI WON SE N PE GBOGBO AWON OMO NAA NI BABA ALAWO ORUNMILA LEYIN O MO PE BABA LAA PE KA TOO PE AWO

OTURA MEJI
PE KA N GBE NU IGBO RUN TE ERE GBA BATA GBA RUN OYE A D IFA FUN ORI OLA A D IFA FUN ORI ISE EBO NI WON NI KO SE ERRO IPO

ERRO OFA ONI ISE KO MA NPE ORI OLA TI RUBO

IRETE MEJI
IWO OTE EMI OTE OTE ODE MEJI ODO OTITO OTE OD EMEJI ODO ODO A D IFA FUN BABA LORI IRE RE MAA LE NSE ERERE IFA JEKI NLORI RERE KI NSE LESE ERERE EBO NI WON NI KO SE O SI GBEBO NBE O RUBO KO I PE KO I JINA E WA BA NI JEBUTU IRE GBOGBO

OSE MEJI
OSE KETE O GBOGUBN NLE AYE O RIN GBAJA O GBOGBO JI ORUNMILA LOUN O FI GBOGBO KELEKELE TOUN SERE A D IFA FUN ORI NIJO TI NSE OHUN GBOGBO TI SEU ODARA SI NAA SE IRE E MI O FUN MI SEU ODARA

SEU ODARA SI NNA SE IRE E MI O FUM MI SEU ODARA

OFUN MEJI
KUDU KUDU KUDU ADO TORI OOGUN SO OOGUN OHUN O SI PO OLOOGUN NI O FOO MU U WA A DIFA FUN ORI ORUNMILA NIGBA TI WON BI ORUNMILA O SE KO LE BAA ROOKO RERE JE LAYE ORUNMILA SI DAGBA DIE SAA O LO TO GEGE KI WON O WA LO REE TA OUN WON BA GBE ORUNMILA LO SODS OBA ALARA EJI ASA Omo AMURIKAN DOKAN AGOGO WON LAWOON FEE TA OJA KAN FUN O WON LERU KAN NI O BA BEERE LOWO ORUNMILA PE KINNI ISE TO MOO SE ORUNMILA LOUN O NISE KAN BOUN BA TI JI OUN A WE OUN O SI KUN OUN O SI BO SORII OTITA OUN A SI JOKOO WON O SI GBE OUNJE WA BA OUN BOUN BA SI TI JEHUN TA OUN O SI MOO SERE O TUN DI LOLA

ALARA LOUN O RA MO ORUNMILA NI WON O MOO GBE OUN LO SODE AJERO WON TUN DODO OUN NAA WON SALAYE OUN NAA LOUN O RA WON BA TUN GBERA O DODO OWARANGUN AGA

ORIKI PARA CONSAGRAO E REZA DIARIA: ORIKI ORI:


r mi srere fun mi r mi srere fun mi r oka ni sanu oka r ejo ni sanu ejo Afo mope ni sanu ope r mi srere fun mi

ORK OR
B o b maa lw, Br lw or re. B o b ma sw, Br lw or re w o. B o b ma kol o, Br lw or re. B o b ma lya o, Br lw or re wo. Or mse pekn d. Ld re ni mi mb. W say mi di rere. Ase.

ORK OR

Or, pl, Att nran Att gbe ni ks. K ss t d n gb lyn or eni. Or pl, Or by, eni or b gbeboo r, k yoss.

ORIKI ORI:
IJUB R O SE, O SE , O SE OS BAB W O SE, O SE , O SE OS BABA W

ORIKI ORI:
ORI BURUKI WU TUULI A KI I DA CSC ASIWEREE MO LOJE ONA A KI MORI OLOYE LAWUJO A DIA FUN MO BOWO TI I SO OBIRIN OGUN ORI TI JUBA LOLA ENI KAN O MO

ORIKI ORI:
ORI LO NDA ENI SEI ONDAYE ORISA LO NPA ENI DA O NPA ORISA DA ORISA LO PA NIDA BI ISU WON SUN AYEMA PA TEMI DA KI ORI MI MA SE ORI KI ORI MI MA GBA ABODI

ORIKI DE EGUNGUN E DOS ODUS QUE CARREGAM EGUNGUN:

Ile mope o o, Akisale mo pe o o, Etigbure mo pe o o, Asa mo pe o o, Eti were ni ti ekute il, Asunmaparada ni tigi aja, Emi Omo re ni mo pe o, Jeki nwa laaye, Maa jeki nku, Maa jeki nri ija igbona, Maa jeki nri ija Ogun, Jowo wa jemi loni, Ki o fire fun mi, Ase. ORIKI EGUN Too ki odn yii O rowa ro ese lai si iyonu Ki o ro wa se owo Ki o ro wa si omo Ki o ro wa si alfia Bi bee ba ni Ki obi o yan o. ORIKI EGUN

T krooro or, en ker e n awr t krooro or, en ker e n awr lss mojub awo lss, lss mn lss mojub awo lss, lses mn lss olwa k a gb o Lss lss mn op ye ye a rok, olwa d a kse, b wa kse

Olwa d se n koja bb rok k k s gun wa lb re Egun bale egun bale, baba egun ati nlo. Egun dara egun dara oni se sun egun dara.

ORIKI EGUN Egungun kiki egungun Baba egun ranran f awo ku opipi O da sobo fun le wo Baba egun bata bango egun de Bi aba fatori na l egun asde

Oriki para egungun


Eegun mope o Iie mope o Etigbure mope o Eti we niti e kete il Asunmanparada niti gi aja Ago kii gbo ekun omore ko man Tati were Eegun abata arago gbale Aroro finju ofofo aye Egungun abala Omo aye Ara orun kinkin Ona mo ni lagba namo nito Abala peleo oba olomo wa bi koribi

1 reza de egungun
IYA NO FE ELEGUN OJARE FELEGUN BODUN BADE MAROMO GBEJO FELEGUN BODUN BADE MALERO I EYIN FELEGUN

OROYI YOODARIWO BEEJE NFELEGUN

2 reza de egungun
OKOKO ADIRE BERE N KOMO YOYO OKOKO

3 reza de egungun
KULUKULU SE OJO TI BALUWE SE WOWO

4 reza de egungun
ESA WON LEGBA OPE TI KOBAYA FEEGUN ESA WON LEGBA

5 reza de egungun
AWA KIISE ALAKISA TIKO ROWO RASO ARAN LOKU TAAFI NDA TIWA

6 reza de egungun
EGUNGUN ODUNPE O EGUNGUN ODUNPE OLE ATI AKARA AKARA OLELE LAFI NSORO NIGBALE EGUNGUN ODUNPE

7 reza de egungun
ENI OJU BANTI KOWOLE OJU KOTIWA ABA BABA RODE ENI OJU BANTI KOWOLE

8 reza de egungun
BABA O BABA O BABA O BABA O YEYE O YEYE O YEYE O YEYE O BABA SO WA NU AWA O RI MO O O SO WA NU AWA O RI MO O YEYE SO WA NU AWA O RI MO O O SO WA NU AWA O RI MO O BI MO RI BABA ORO MI A DUN BI OYIN BI MO RI YOYO ORO MI A DUN BI OYIN JOUN N GBOGBO ALAPALAOMO A SUS MO SA JOUN N GBOGBO KO TO BERE KO TO MO BUKA JOUN N GBOGBON AWON OMO LA NI WON YI A O MO WON AWON OMO LA NI WON YI A O MO WON DIGBOLU KOLU DIGBOLU KOLU BO O BA DIGBOLU N O PADE TEHIN RE O DISGOLU KOLU DISBOLU KOLU IGBA O MO O JO TETE NDE KO OO JO O KO BI ENI RO RO BI ENI KO BE RO BI ENI KO BE KO BI ENI RO WA LA WA MO DO ORO AWA M ODO JO BI AGBEGI JO BI AGBEJI JO

IGBA TI IWO MO O JO O TETE NDE TETE NDE O E TUN GBE TETE NDE O E TUN GBE TETE NDE TETE NDE KO OO JO O BO BA TI DPATI OPONA ATATA TETE NDE TETE NDE

ORIKI EGUNGUN
EGUNGUN A YE KII SE BO ORUN MO JUBA RE EGUNGUN MONRIWO ILE MO PE O GBOGO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O A KII DE WA O A KII E EGUNGUN ILE MO PE O WON GBOGBO ARA ASIWAJU AWO WON GBOGBO ARAALE ASIWAJU MI GBOGBO MONRIWO ILE MO PO O EGUNGUN O MO PE GBOGBO ENYIN SI FUN MI AABO ATI IRONLOWO AGO KII NGBO EKUN OMO RE ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O KI O MA TA ETI WERE BABA AWA OMO RE NI A NPE O ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O KI O SARE WA JE WA O KI O GBO IWURE WA ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O MA JE A RIKU EWE MA JE A RIJA SEU JE A RIJA OGUN MA JE A RIJA OMI MA JE A RIJA SOPONNA ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PE O EGUNGUN O MO TUMBA BABA ILE MO PE O GBOGBO MONRIWO ILE MO PO O EGUNGUN O ILE MO PE

O GBOGBO MONTIWO ILE MO PE O EGUNGUN O EGUNGUN O EGUNGUN ILE MO PE O EGUNGUN O

Das könnte Ihnen auch gefallen