Sie sind auf Seite 1von 2

ATAARE ____________ PIMIENTA

ATAARE RE O
ATAARE KI NDI TIRE LABOO
DINDIN NI ATATE NDI TIRE
O KO NI DI TIRE LABO
OPOLOPO OMO NI ATARE NI
WA LOMO LOPO
WA LOWO LOPO
WA NI ALAFIA LOPO
WA NI OHUN GBOGBO LOPO
OYIN __________ MIEL
OYIN NI YI O
KI AYE RE DUN TITI BI OYIN
DINDUN DINDUN NI A MAA NBA AFARA OYIN
AYE RE YIO MAA DUN
A KO NI RI OUN IBAJE NI ILE AYE RE

IREKE (cana de aucar) ____________


IREKE NI YI
KI ARE RE NI ADUN
KI AYE NI AYO
KI AYE NI OLA

OBI KOLA- OBI KOLA


obi ni yi o o
obi ni nbe iku
obi ni nbe arun
obi ni nbe ejo
oun naa ni nbe ota
a ba e, be gbogbo ohun buruku ile aiye
OROGBO OROGBO
orogbo re o
orogbo ni in eni saye

wa gbo, in l laye
ki o to lo si ibi ti gba nre
aiye o ni se e ni abiku fun awo obi re

Das könnte Ihnen auch gefallen