Sie sind auf Seite 1von 4

Amulu

Odu

Ogbe-Oyeku
Ogbe Yeku ni baba ml
Or Ogbo, or at ni baba edan
sr ni baba j
D fn Alr-nsod
Ti nmj ekun snrhn omo
Wn n k skal, ebo n sse
gbebo, o rbo
K p k jnn
E w b ni lk kangiri
k kangiri l b ni ls Obrs.
2
Ogbe Yeku baba ml
Or Ogb, or at ni baba edan
sr ni baba j
D fn s-Nl srmgb
Ti n mj ekun snrhn ire gbogbo.
Wn n k skal,ebo n sse
gbebo, rbo
K p, K jnn
K w b ni b jbt ire gbogbo.
Ogbe-Iwori (Ogbe-wo hin)
Ogbe wo hin wo
baja r o pakun
a difa fun Ekuya
eyi ti n awo re ahoro ile baba r,
ti n l re jogbo, ti n l re jat.
b ni wn ni [k]o e,
o si gbe b nb, o rub.
Riru b ni fi ti n gbe ni.
Aitete ru teu a da ladanu.
Ko p, ko jinna,
Ifa wa ba mi laarin igun,

aarin igun laa ba ni ls baria.


yin wo Ifa ti awo ki bi ti n .

2
Aiju whin obinrin awo apo
aiju whin kunrin awo am,
igba elepo abhin manamana
a difa fun onile eti odo
eyi ti n mnuju e rahun nitori m.
b ni wn ni ko e,
o si gbb nib o rub.
Ko p, ko jinna,
yin awofa j bi ti n .
Ko p, ko jinna,
Ifa wa ba ni ni jbutu m,
jbutu m laa ba ni ls baria.
ba wa ki yeye o.
Yeye o a fid rm.
un yeye o, a fid rm.
ba wa ki yeye o, a fid rm.
un yeye o, a fid rm.

Ogbe-Odi
n wiriwiri Ogbe 'Di
la wiriwiri Ogbe 'Di
tooto eeyan laa beere
Ka tii beere Ogeben 'Di
Dia fun Olukoyin
Won n fi ojo ikuu re d rn
Id w d mo lsrun-n mi
n ib n ko d K fn If sil
2
n wiriwiri Ogbe 'Di
n wiriwiri Ogbe 'Di
Ogb 'D lyin n l bwny
Eye ni t fap s'Ogn
gblgb wd t hu'm lyn
D fn baba Arugbo
Kk k p
y t n se ekul, yin nifa d?
Gnnugn ki k lewe
Kangere
Ma Dagba ma dargbo

Kangere
l k b'gi Oko w'w
Kangere
Ma Dagba ma dargb
Kangere
Apada lo niki gbogbo ibi o pada leyin mi
Kangere
Ma Dagba ma dargbo
Kangere

Ogbe-Irosun
Yangi ile a bori gungun
a difa fun Ogbe
eyi ti n l re dawo osun sil nile Alara.
b ni wn ni [k]o e,
o si gbe b nb, o rub.
Riru b ni fin ti n gbe ni.
Aitete ru teu a da ladanu.
Ko p, ko jinna,
wa wo Ifa awo ki bi ti n .
2
Ina roke ni n jo mi roro mi roro.
Otura akur a bi m ri gbin gbin
m ri gbin gbin gbin,
a dia fun Layewu eyi ti e obinrin Okete,
abu fun Omio, ti e obinrin dun,
a dia fun Amaehun, eyi ti obinrin Ore.

Das könnte Ihnen auch gefallen