Sie sind auf Seite 1von 1

OBARAKEJIKAN/OBARA OKANRAN.

Good morning my people, how was your night? Hope it was splendid. As we are going
out today our head will lead us to the path of success, we shall never experience
inconvenience amen.
It is OBARAKEJIKAN/OBARA OKANRAN that revealed out this morning, ifa
advised whoever this corpus revealed out for that he/she should make a sacrifice very
well in order to avoid brutal sickness that may lead to madness, especially, ifa talked
about a woman here that her husband should not relent effort on her so that she would
never completely become mad.
Hear what the corpus said: obarakejikan cast divined for ororo the wife of a king when
she was sick, when ororo saw white something she will called it red when she saw black
human being she will called it light, ororo was acted madness, when the king noticed
that the sickness is going beyond expectation he went to consult ifa and he was advised
to offer a sacrifice, two kola nuts, corn cake, cake beans, he-goat, yam, corn and ifa
leaves and the king complied aftermath, ororo the wife of the king became healed, she
back to her sense and she was able to recognised everything correctly, she started
dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising
God.
My people, I pray this morning that we shall never experience any sickness that will
turn to madness, our brains will never be contaminated our wives will never experience
madness by the authority given to orunmila bara agbonmiregun amen.
YORUBA VERSION: Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Mo gbaladura laaro yi wipe bi
a se njade lo Ori wa yio muwa rin ona ise rere loni ako ni jaye inira o ase.
Odu ifa to gate laaro yi ni OBARA KEJIKAN/ OBARA OKANRAN, ifa yi gba eniti
odu yi ba jade si niyanju ki o rubo daadaa o ifa so wipe oun koni jeki onitohun rogun
aisan ode ori ti yio maa mu so kantankantan o, ifa yi ti e ba olobinrin eni soro wipe ki
Oko re mase dake adura lori re ki iyawo re ma ba se aisan ti yio fi ya were patapata
Ifa naa ki bayi wipe: obarakejikan a difa fun ororo eyiti nse aya olofin nigbati o nse
ogbogbo aisan nle, bi ororo ba ri eniyan dudu yio maa pe ni eniyan pupa bi o ba ri
eniyan pupa yio maa pe ni alawo funfun ororo bere sini so kantankantan olofin lo wa
gboko alawo lo won wa ni ebo ni ki olofin lo ru obi meji, igiripa obuko esu, eru isu, eru
eka, eru eko, eru akara ati igba ewe ayajo ifa olofin kabomora o rubo ko pe ko jina ara
iyawo re ba ya ko wa so kantankantan mo opolo re wa pada sini sise daadaa bi ti
ateyinwa o wa njo o wa nyo o nyin awo awo nyin ifa, ifa nyin eledumare o ni nje riru
ebo a maa gbeni arukesu a maa da ladaju ko pe ko jina ifa wa bami larusegun arusegun
ni a nba awo lese obarisa.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe ako ni ri ogun aisan aagana o, ori wa koni
daru o aisan buburu koni kolu iyawo wa lagbara Orunmila bara agbonmiregun aseee.
ABORU ABOYE OOO.