Sie sind auf Seite 1von 8

Ebo riru / Ifa adabo Mo wari fun Isese

Ebo riru

Steps to be taken when we make ebo.

The Odu to make its ebo is written in the center of the opon whereby the other Odu adabo will be in the right and left side of the Odu. Osetura is alwas at the right side. Place on the board grains of corn or cut of obi, and money (owow ileru) for ebo. If you wants to use opele, you place on ite, then open the Odu, place grain of maize , money and necessary materials at the midle of opele. Then start with this oriki.

Agonrin igboro ko yoo lee tee Ko ma baa deranIgun Ko ma baa deran Aje Ko ma baaderan iyamin A difa fun Ajagbey Tii won o mu lo igbodu lo te nIfa Babalawo kii ruku ogberi Ogberi kii wo igbodu laisawo Olokuu ko nii gba ki won o wo oku oun Ifa lo di Obiri Mo lo dapada se Oferegege Ajagbe dide o

Oferegege Bi ewure bi'mo Loojo, oojo nii dide Oferegege Ajagbe to Dide or Oferegege Aguntan Ba bimo Loojo lo ndide Oferegege Ajagbe to dide o Oferegege Adie okoko bimo Loojo, ojo lo dide Oferegege Ajagbe dide o Oferegege Bi iku nbo jooko te, Bi arun, ofo , ese, egba, gbogbo ajogun nbo jokoo te won. Ti ire aje, aya, oko, omo oun ire gbogbo nbo je kim o to awo lowo. Oun a ba te male laa siju wo Siju aje, aya, omo ati ire gbogbo wo awo

You then pay homage to the babalawo present in the programm;

Awodi lo lapa O fese eyin jale Difa fun Olofin alukuuji Ohun awo fowo ba ki o debo Iroke fowo ba a Iruke fowo ba a

The awo present there will toch or point to the a boe as a sine of participation.

You the recite this one verse of odu Okanran osa to bless the hands that will make the EBO. The verse is as follows: Otun strip (the right hand is placed on the opon) Awo won Ode Aba A difa fun won lode Aba Ekun Aje, aya, oun ire gbogbo ni won nsun. Ebo ni won ni won o se Won gbebo, won rubo Ko pe ko jinn Ire wa ire gbogbo je de tuturu Osi pele (left hand is placed on the dashboard) Awo won lode Abose Difa fun won lode fun Abose Ekun ire gbogbo won nsun Ebo ni won won o se Won gbebo. Won rubo Kee kee pe jinna Ire ire gbogbo wa je de tuturu Atotun atosi kii sebo aifin A difa fun Aseweleri Omo okunrin depenu O di depenu, depenu A ba degun depe, lawo lori Ko lee ran awo. Asewele de, Omokunrin depenu.

Moves money and corn while praying the verse of Sa Okana odu for the client to achieve the purpose for which it does eb:

Ori ade nii sopon Awon odale nii rin ihoho Sosin sora Idanndan nii fi ara re se afara olukoyin Difa fun Akoworari Tii somo Ajaniwarun Akoworari kii ku Eniyan to kowo rari A si gbsdun

After this oriki, you use the money rubs his forehead and chest and place the customer money under the table of Ifa.

The following verses are recited to ensure that the will eb be accepted and protects you from all evil:

Gbami igbo lawo gbami Igbo Gbami odan lawo gbami odan Gbami oheehee ni sawo gbami ohenhen Ifa to ba gba mi nibi o di gagaaga Bi mo ba de ibi to sunwoni Maa sesan fun o A difa fun Orunmila Ifa o yo omo re ninu ibi Owo mi wa bewe oloboyoboyo temi wayi

Okosokoso Nifa o yomo Re kuro ninu ibi Okosokoso

The verse that follows will pray between verse and verse of each odu for indicate the end of a sign and the beginning of another sign, and is used to call IFA eb accepting. As he reads the verse will touch the forehead and chest with corn.

Ifin re ni kebo ofin Idaare ni ki ebo da Kebo fiin ire Kebo daare Bara Agbonniregun.

Then you recite this oriki from Oturakunkaa;

Okin ningin ningin awo Olokun A difa fun Olokun Nijo omi okun ko to bu boju Aluko dodoodo awoOlosa A difa fun Olosa Lojo omo osa ko toobu sinse Odidere abirin ese Kerewekerewe A dira fun Oluwo omo odo oba Atorun gbegba aje kari waye Otu waraka o da waraka

Erigi awo agbasa A difa fun won niseagere Nijo won nfohun ebo rubo A rohun ebo loni ki ebo o fin Erigin awo agbasaa Ifa a rohun ebo Eko to nbe nile yii nko? Ohun ebo ni Erigi awo agbasa Ifa a rohun ebo Epo, owo, oti (and other maaterials) to nbe nile yii nko? Ohun ebo ni Erigi awo agbasa Ifa, rihun ebo Ifa a ti rihun ebo Egungun Akodo, Egungun edidaare Bi oloti ba ponti, oda nii da Parada parada lobinrin roko Ifa a ti rihun ebo Dadaa nii sadiye aba Erigi lawo agbasa Ifa a ti rihun ebo Danidani lasiwere nrin Erigi lawo agbasa Ifa a rihun ebo Eni ba lebo mo da, ki o maa bebe lo

Erigi lawo agbasa Ifa a rihun ebo

This oriki is recited to pay homage to the ancestors Okun su narenare Osa kun lengbelengbe Alaye nraye Awon agbaagba wo igbeyin oro Won ri pe ko sunwon mo Won fi irun dimu Won irungbon diya pinpinpin A difa fun Isese Tii solorimoro lorun Nje kini Isese eni? Baba eni isese eni Iye eni ni isese eni Ori eni ni isese eni Oluwo eni isese eni Olodumare ni isese eni Isese la o bo ki a to bo orisa

After all these, we are to recite oriki from the odu that we are making its ebo. We recite as many oriki as we can from thie particular odu. Then we recite oriki from the opposite Odu. For example, if the odu we are the the ebo is Iwori ogbe the opposite is Ogbe weyin. Then we recite oriki from the Odu adabo. The odu adabo are; Ejiogbe to Ofun meji, if time permit but if not ejiogbe to odi meji is allright. O thers include; Owanrinsogbe, obarabogbe, okanransode. Ogundasoriire,Oyekulogbe,Osewori, osebirete, ika meji, Irete meji . The last odu is Osetura.

You then put epo pupa, omi to the ebo. We ask if is alright. Thwn we print on opon odu Okanran Osa, say the necessary oriki there.

Take the ebo to Esu or ask the place with ibo we to place the ebo.

For oriki Ifa adabo contact; otunbaifa@yahoo.com +2348033866387.

Das könnte Ihnen auch gefallen